Diutarónómì 28:64 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 64 “Jèhófà máa tú ọ ká sáàárín gbogbo orílẹ̀-èdè, láti ìkángun kan ayé dé ìkángun kejì ayé,+ o sì máa ní láti sin àwọn ọlọ́run tí wọ́n fi igi àti òkúta ṣe níbẹ̀, àwọn ọlọ́run tí ìwọ àtàwọn baba ńlá rẹ kò mọ̀.+ Nehemáyà 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Jọ̀ọ́, rántí ọ̀rọ̀ tí o pa láṣẹ fún* Mósè ìránṣẹ́ rẹ pé: ‘Tí ẹ bá hùwà àìṣòótọ́, màá fọ́n yín ká sáàárín àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè.+
64 “Jèhófà máa tú ọ ká sáàárín gbogbo orílẹ̀-èdè, láti ìkángun kan ayé dé ìkángun kejì ayé,+ o sì máa ní láti sin àwọn ọlọ́run tí wọ́n fi igi àti òkúta ṣe níbẹ̀, àwọn ọlọ́run tí ìwọ àtàwọn baba ńlá rẹ kò mọ̀.+
8 “Jọ̀ọ́, rántí ọ̀rọ̀ tí o pa láṣẹ fún* Mósè ìránṣẹ́ rẹ pé: ‘Tí ẹ bá hùwà àìṣòótọ́, màá fọ́n yín ká sáàárín àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè.+