-
Ẹ́kísódù 18:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Bàbá ìyàwó Mósè sọ fún un pé: “Ohun tí ò ń ṣe yìí kò dáa. 18 Ó máa tán ìwọ àtàwọn èèyàn tó wà pẹ̀lú rẹ lókun, torí ẹrù yìí ti pọ̀ jù fún ọ, o ò lè dá rù ú.
-
-
Nọ́ńbà 11:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Mósè wá sọ fún Jèhófà pé: “Kí ló dé tí o fìyà jẹ ìránṣẹ́ rẹ? Kí ló dé tí o kò ṣojúure sí mi, tí o sì di ẹrù gbogbo àwọn èèyàn yìí lé mi lórí?+
-