-
Nọ́ńbà 35:22-24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 “‘Àmọ́ tó bá jẹ́ pé ńṣe ló ṣèèṣì tì í, tí kì í ṣe pé ó kórìíra rẹ̀ tàbí tó ju nǹkan lù ú láì gbèrò ibi+ sí i,* 23 tàbí tó ṣèèṣì sọ òkúta lù ú láìmọ̀ pé ó wà níbẹ̀, tí kì í sì í ṣe pé ọ̀tá rẹ̀ ni tàbí pé ó fẹ́ ṣe é léṣe, tí ẹni náà sì kú, 24 kí àpéjọ náà tẹ̀ lé ìdájọ́+ wọ̀nyí láti dá ẹjọ́ ẹni tó pààyàn àti ẹni tó ń gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀.
-