-
Diutarónómì 1:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ní agbègbè Jọ́dánì ní ilẹ̀ Móábù, Mósè bẹ̀rẹ̀ sí í ṣàlàyé Òfin+ yìí, pé:
-
-
Diutarónómì 3:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Ìgbà tí à ń gbé ní àfonífojì tó wà níwájú Bẹti-péórì+ ni gbogbo èyí ṣẹlẹ̀.
-