Ẹ́kísódù 16:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ẹ kíyè sí i pé Jèhófà ti fún yín ní Sábáàtì.+ Ìdí nìyẹn tó fi fún yín ní oúnjẹ ọjọ́ méjì ní ọjọ́ kẹfà. Kí kálukú dúró sí ibi tó bá wà; ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ kúrò ní agbègbè rẹ̀ ní ọjọ́ keje.”
29 Ẹ kíyè sí i pé Jèhófà ti fún yín ní Sábáàtì.+ Ìdí nìyẹn tó fi fún yín ní oúnjẹ ọjọ́ méjì ní ọjọ́ kẹfà. Kí kálukú dúró sí ibi tó bá wà; ẹnikẹ́ni ò gbọ́dọ̀ kúrò ní agbègbè rẹ̀ ní ọjọ́ keje.”