Ẹ́kísódù 20:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,+ kí ẹ̀mí rẹ lè gùn lórí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa fún ọ.+ Éfésù 6:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,”+ èyí ni àṣẹ kìíní pẹ̀lú ìlérí: 3 “Kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún ọ,* kí o sì lè pẹ́ láyé.”
2 “Bọlá fún bàbá rẹ àti ìyá rẹ,”+ èyí ni àṣẹ kìíní pẹ̀lú ìlérí: 3 “Kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún ọ,* kí o sì lè pẹ́ láyé.”