Ẹ́kísódù 20:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè.+ 1 Kọ́ríńtì 6:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ẹ máa sá fún ìṣekúṣe!*+ Gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ míì tí èèyàn lè dá wà lóde ara rẹ̀, àmọ́ ẹni tó bá ń ṣe ìṣekúṣe ń ṣẹ̀ sí ara òun fúnra rẹ̀.+ Hébérù 13:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kí ìgbéyàwó ní ọlá láàárín gbogbo èèyàn, kí ibùsùn ìgbéyàwó má sì ní ẹ̀gbin,+ torí Ọlọ́run máa dá àwọn oníṣekúṣe* àti àwọn alágbèrè lẹ́jọ́.+
18 Ẹ máa sá fún ìṣekúṣe!*+ Gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ míì tí èèyàn lè dá wà lóde ara rẹ̀, àmọ́ ẹni tó bá ń ṣe ìṣekúṣe ń ṣẹ̀ sí ara òun fúnra rẹ̀.+
4 Kí ìgbéyàwó ní ọlá láàárín gbogbo èèyàn, kí ibùsùn ìgbéyàwó má sì ní ẹ̀gbin,+ torí Ọlọ́run máa dá àwọn oníṣekúṣe* àti àwọn alágbèrè lẹ́jọ́.+