ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 20:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 “O ò gbọ́dọ̀ jalè.+

  • Léfítíkù 19:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ jalè,+ ẹ ò gbọ́dọ̀ tanni jẹ,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ hùwà àìṣòótọ́ sí ara yín.

  • Òwe 30:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Mú kí àìṣòótọ́ àti irọ́ jìnnà sí mi.+

      Má ṣe fún mi ní òṣì tàbí ọrọ̀.

      Ṣáà jẹ́ kí n jẹ ìwọ̀nba oúnjẹ tí ó tó mi,+

       9 Kí n má bàa yó tán, kí n sì sẹ́ ọ, kí n sọ pé, “Ta ni Jèhófà?”+

      Má sì jẹ́ kí n tòṣì, kí n wá jalè, kí n sì kó ìtìjú bá* orúkọ Ọlọ́run mi.

  • 1 Kọ́ríńtì 6:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 àwọn olè, àwọn olójúkòkòrò,+ àwọn ọ̀mùtípara,+ àwọn pẹ̀gànpẹ̀gàn* àti àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run.+

  • Éfésù 4:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Kí ẹni tó ń jalè má jalè mọ́; kàkà bẹ́ẹ̀, kó máa ṣiṣẹ́ kára, kó máa fi ọwọ́ rẹ̀ ṣe iṣẹ́ rere,+ kó lè ní nǹkan tó máa fún ẹni tí kò ní.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́