ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 6:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Kí o fetí sílẹ̀, ìwọ Ísírẹ́lì, kí o sì rí i pé ò ń pa wọ́n mọ́, kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún ọ, kí o sì lè pọ̀ rẹpẹtẹ ní ilẹ̀ tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn, bí Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá rẹ ṣe ṣèlérí fún ọ gẹ́lẹ́.

  • Diutarónómì 6:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 A ó sì kà wá sí olódodo tí a bá rí i pé gbogbo àṣẹ yìí là ń pa mọ́ láti fi hàn pé à ń ṣègbọràn sí* Jèhófà Ọlọ́run wa, bó ṣe pa á láṣẹ fún wa.’+

  • Diutarónómì 8:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 “Ẹ rí i pé ẹ̀ ń tẹ̀ lé gbogbo àṣẹ tí mò ń pa fún yín lónìí, kí ẹ lè máa wà láàyè,+ kí ẹ máa pọ̀ sí i, kí ẹ sì wọ ilẹ̀ tí Jèhófà búra nípa rẹ̀ fún àwọn baba ńlá yín kí ẹ lè gbà á.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́