ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 5:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 O ò gbọ́dọ̀ ní ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.*+

  • Àìsáyà 42:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Èmi ni Jèhófà. Orúkọ mi nìyẹn;

      Èmi kì í fi ògo mi fún ẹlòmíì,*

      Èmi kì í sì í fi ìyìn mi fún àwọn ère gbígbẹ́.+

  • Sekaráyà 14:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Jèhófà yóò sì jẹ́ Ọba lórí gbogbo ayé.+ Jèhófà yóò jẹ́ ọ̀kan ní ọjọ́ yẹn,+ orúkọ rẹ̀ yóò sì jẹ́ ọ̀kan.+

  • Máàkù 12:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Jésù dáhùn pé: “Àkọ́kọ́ ni, ‘Gbọ́, ìwọ Ísírẹ́lì, Jèhófà* Ọlọ́run wa, Jèhófà* kan ṣoṣo ni,

  • Máàkù 12:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Akọ̀wé òfin náà sọ fún un pé: “Olùkọ́, ohun tí o sọ dáa, ó sì bá òtítọ́ mu, ‘Ọ̀kan ṣoṣo ni Òun, kò sí ẹlòmíì àfi òun nìkan;+

  • 1 Kọ́ríńtì 8:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 ní tiwa, Ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà,+ Baba,+ ọ̀dọ̀ ẹni tí ohun gbogbo ti wá, tí àwa náà sì wà fún un;+ Olúwa kan ló wà, Jésù Kristi, ipasẹ̀ ẹni tí ohun gbogbo fi wà,+ tí àwa náà sì wà nípasẹ̀ rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́