Jóṣúà 24:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mo wá fún yín ní ilẹ̀ tí ẹ ò ṣiṣẹ́ fún àti àwọn ìlú tí ẹ ò kọ́,+ ẹ sì ń gbé inú wọn. Ẹ tún ń jẹ àwọn èso ọgbà àjàrà àti àwọn èso igi ólífì tí ẹ ò gbìn.’+ Sáàmù 105:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Ó fún wọn ní ilẹ̀ àwọn orílẹ̀-èdè;+Wọ́n jogún ohun tí àwọn míì ti ṣiṣẹ́ kára láti mú jáde,+
13 Mo wá fún yín ní ilẹ̀ tí ẹ ò ṣiṣẹ́ fún àti àwọn ìlú tí ẹ ò kọ́,+ ẹ sì ń gbé inú wọn. Ẹ tún ń jẹ àwọn èso ọgbà àjàrà àti àwọn èso igi ólífì tí ẹ ò gbìn.’+