-
Diutarónómì 4:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 “Ní báyìí, ẹ̀yin ọmọ Ísírẹ́lì, ẹ fetí sí àwọn ìlànà àti àwọn ìdájọ́ tí mò ń kọ́ yín láti pa mọ́, kí ẹ lè máa wà láàyè,+ kí ẹ lè wọ ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá yín máa fún yín, kí ẹ sì gbà á.
-
-
Gálátíà 3:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Òfin kò dá lórí ìgbàgbọ́. Àmọ́, “yóò mú kí ẹni tó bá ń pa àwọn ohun tó sọ mọ́ wà láàyè.”+
-