Diutarónómì 16:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “O ò gbọ́dọ̀ gbin igi èyíkéyìí láti fi ṣe òpó òrìṣà*+ sẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ tí o ṣe fún ara rẹ. 22 “O ò sì gbọ́dọ̀ ṣe ọwọ̀n òrìṣà fún ara rẹ,+ torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ kórìíra rẹ̀.
21 “O ò gbọ́dọ̀ gbin igi èyíkéyìí láti fi ṣe òpó òrìṣà*+ sẹ́gbẹ̀ẹ́ pẹpẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ tí o ṣe fún ara rẹ. 22 “O ò sì gbọ́dọ̀ ṣe ọwọ̀n òrìṣà fún ara rẹ,+ torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ kórìíra rẹ̀.