Diutarónómì 33:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Aláyọ̀ ni ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì!+ Ta ló dà bí rẹ,+Àwọn èèyàn tó ń gbádùn ìgbàlà Jèhófà,+Apata tó ń dáàbò bò ọ́,+Àti idà ọlá ńlá rẹ? Àwọn ọ̀tá rẹ máa ba búrúbúrú níwájú rẹ,+Wàá sì rìn lórí ẹ̀yìn* wọn.” Sáàmù 147:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kò ṣe bẹ́ẹ̀ fún orílẹ̀-èdè míì;+Wọn ò mọ nǹkan kan nípa ìdájọ́ rẹ̀. Ẹ yin Jáà!*+
29 Aláyọ̀ ni ọ́, ìwọ Ísírẹ́lì!+ Ta ló dà bí rẹ,+Àwọn èèyàn tó ń gbádùn ìgbàlà Jèhófà,+Apata tó ń dáàbò bò ọ́,+Àti idà ọlá ńlá rẹ? Àwọn ọ̀tá rẹ máa ba búrúbúrú níwájú rẹ,+Wàá sì rìn lórí ẹ̀yìn* wọn.”