Jóṣúà 11:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Gbogbo ẹrù àwọn ìlú yìí àti ẹran ọ̀sìn wọn ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kó fún ara wọn.+ Àmọ́ wọ́n fi idà pa gbogbo èèyàn títí wọ́n fi pa gbogbo wọn run.+ Wọn ò dá ẹnikẹ́ni tó ń mí sí.+
14 Gbogbo ẹrù àwọn ìlú yìí àti ẹran ọ̀sìn wọn ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kó fún ara wọn.+ Àmọ́ wọ́n fi idà pa gbogbo èèyàn títí wọ́n fi pa gbogbo wọn run.+ Wọn ò dá ẹnikẹ́ni tó ń mí sí.+