ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 16:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Lẹ́yìn náà, Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Màá rọ̀jò oúnjẹ fún yín láti ọ̀run,+ kí kálukú máa jáde lọ kó iye tó máa tó o lójoojúmọ́,+ kí n lè dán wọn wò, kí n sì rí i bóyá wọ́n á pa òfin mi mọ́ tàbí wọn ò ní pa á mọ́.+

  • Ẹ́kísódù 20:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Mósè wá sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ má bẹ̀rù, torí ṣe ni Ọlọ́run tòótọ́ wá dán yín wò,+ kí ẹ lè máa bẹ̀rù rẹ̀ kí ẹ má bàa ṣẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́