Nọ́ńbà 13:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 A rí àwọn Néfílímù níbẹ̀, àwọn ọmọ Ánákì,+ tí wọ́n jẹ́ àtọmọdọ́mọ* àwọn Néfílímù. Lójú wọn, ṣe la dà bíi tata, bẹ́ẹ̀ náà ló sì rí lójú tiwa.”
33 A rí àwọn Néfílímù níbẹ̀, àwọn ọmọ Ánákì,+ tí wọ́n jẹ́ àtọmọdọ́mọ* àwọn Néfílímù. Lójú wọn, ṣe la dà bíi tata, bẹ́ẹ̀ náà ló sì rí lójú tiwa.”