Ẹ́kísódù 24:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Mósè wá wọ inú ìkùukùu náà, ó sì lọ sórí òkè náà.+ Mósè sì dúró lórí òkè náà fún ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru.+
18 Mósè wá wọ inú ìkùukùu náà, ó sì lọ sórí òkè náà.+ Mósè sì dúró lórí òkè náà fún ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru.+