Nọ́ńbà 11:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n wá pe orúkọ ibẹ̀ ní Tábérà,* torí pé iná látọ̀dọ̀ Jèhófà jó wọn.+