- 
	                        
            
            Diutarónómì 4:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        36 Ó mú kí o gbọ́ ohùn rẹ̀ láti ọ̀run, kó lè tọ́ ọ sọ́nà, ó mú kí o rí iná ńlá rẹ̀ ní ayé, o sì gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀ látinú iná.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Diutarónómì 5:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        4 Ojúkojú ni Jèhófà bá yín sọ̀rọ̀ ní òkè náà látinú iná.+ 
 
-