ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 20:23, 24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Jèhófà wá sọ fún Mósè àti Áárónì ní Òkè Hóórì létí ààlà ilẹ̀ Édómù pé: 24 “Wọ́n máa kó Áárónì jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀.*+ Kò ní wọ ilẹ̀ tí màá fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, torí pé ẹ̀yin méjèèjì ṣe ohun tó lòdì sí àṣẹ tí mo pa nípa omi Mẹ́ríbà.+

  • Nọ́ńbà 33:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Wọ́n wá kúrò ní Mósérótì, wọ́n sì pàgọ́ sí Bẹne-jáákánì.+

  • Nọ́ńbà 33:38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 38 Àlùfáà Áárónì wá gun Òkè Hóórì lọ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ, ó sì kú síbẹ̀ ní ọjọ́ kìíní, oṣù+ karùn-ún, ọdún ogójì tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́