- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 14:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 Jèhófà fúnra rẹ̀ máa jà fún yín,+ ẹ ó sì dákẹ́ jẹ́ẹ́.” 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Jóṣúà 10:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        42 Ìgbà kan náà ni Jóṣúà ṣẹ́gun àwọn ọba yìí àti gbogbo ilẹ̀ wọn, torí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ló ń jà fún Ísírẹ́lì.+ 
 
-