-
Ẹ́kísódù 18:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Mo ti wá mọ̀ báyìí pé Jèhófà tóbi ju gbogbo ọlọ́run yòókù lọ+ torí ohun tó ṣe sí àwọn tí kò ka àwọn èèyàn rẹ̀ sí.”
-
-
2 Kíróníkà 2:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ilé tí mo fẹ́ kọ́ náà máa tóbi, nítorí Ọlọ́run wa tóbi ju gbogbo àwọn ọlọ́run míì lọ.
-
-
Sáàmù 97:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Nítorí pé, ìwọ Jèhófà ni Ẹni Gíga Jù Lọ lórí gbogbo ayé;
O ga fíìfíì ju gbogbo àwọn ọlọ́run yòókù.+
-