Ìṣe 10:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ni Pétérù bá bẹ̀rẹ̀ ọ̀rọ̀, ó ní: “Ní báyìí, ó ti wá yé mi dáadáa pé Ọlọ́run kì í ṣe ojúsàájú,+ Róòmù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí kò sí ojúsàájú lọ́dọ̀ Ọlọ́run.+