Sáàmù 68:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bàbá àwọn ọmọ aláìníbaba àti ẹni tó ń dáàbò bo* àwọn opó+Ni Ọlọ́run nínú ibùgbé rẹ̀ mímọ́.+ Jémíìsì 1:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ìjọsìn* tó mọ́, tí kò sì ní ẹ̀gbin lójú Ọlọ́run àti Baba wa nìyí: láti máa bójú tó àwọn ọmọ aláìlóbìí+ àti àwọn opó+ nínú ìpọ́njú wọn,+ ká sì máa pa ara wa mọ́ láìní àbààwọ́n nínú ayé.+
27 Ìjọsìn* tó mọ́, tí kò sì ní ẹ̀gbin lójú Ọlọ́run àti Baba wa nìyí: láti máa bójú tó àwọn ọmọ aláìlóbìí+ àti àwọn opó+ nínú ìpọ́njú wọn,+ ká sì máa pa ara wa mọ́ láìní àbààwọ́n nínú ayé.+