Léfítíkù 19:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Bákan náà, ẹ ò gbọ́dọ̀ kó àwọn ohun tó ṣẹ́ kù sílẹ̀ nínú ọgbà àjàrà yín tàbí kí ẹ ṣa àwọn èso àjàrà tó fọ́n ká sínú ọgbà àjàrà yín. Ẹ fi í sílẹ̀ fún àwọn aláìní*+ àti àjèjì. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín. Diutarónómì 24:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “O ò gbọ́dọ̀ rẹ́ alágbàṣe tó jẹ́ aláìní àti tálákà jẹ, ì báà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn arákùnrin rẹ tàbí àjèjì tó wà ní ilẹ̀ rẹ, nínú àwọn ìlú* rẹ.+ Sáàmù 146:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà ń dáàbò bo àwọn àjèjì;Ó ń fún ọmọ aláìníbaba àti opó lókun,+Àmọ́, ó ń sọ èrò àwọn ẹni burúkú dòfo.*+
10 Bákan náà, ẹ ò gbọ́dọ̀ kó àwọn ohun tó ṣẹ́ kù sílẹ̀ nínú ọgbà àjàrà yín tàbí kí ẹ ṣa àwọn èso àjàrà tó fọ́n ká sínú ọgbà àjàrà yín. Ẹ fi í sílẹ̀ fún àwọn aláìní*+ àti àjèjì. Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.
14 “O ò gbọ́dọ̀ rẹ́ alágbàṣe tó jẹ́ aláìní àti tálákà jẹ, ì báà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn arákùnrin rẹ tàbí àjèjì tó wà ní ilẹ̀ rẹ, nínú àwọn ìlú* rẹ.+
9 Jèhófà ń dáàbò bo àwọn àjèjì;Ó ń fún ọmọ aláìníbaba àti opó lókun,+Àmọ́, ó ń sọ èrò àwọn ẹni burúkú dòfo.*+