Nọ́ńbà 14:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Síbẹ̀, kò sí ìkankan nínú àwọn tó fojú rí ògo mi àti àwọn iṣẹ́ àmì+ mi tí mo ṣe ní Íjíbítì àti ní aginjù, tó tún wá ń dán mi wò+ nígbà mẹ́wàá yìí, tí kò sì fetí sí ohùn mi,+
22 Síbẹ̀, kò sí ìkankan nínú àwọn tó fojú rí ògo mi àti àwọn iṣẹ́ àmì+ mi tí mo ṣe ní Íjíbítì àti ní aginjù, tó tún wá ń dán mi wò+ nígbà mẹ́wàá yìí, tí kò sì fetí sí ohùn mi,+