Jẹ́nẹ́sísì 46:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ọmọ méjì* ni Jósẹ́fù bí ní Íjíbítì. Gbogbo ará* ilé Jékọ́bù tó wá sí Íjíbítì jẹ́ àádọ́rin (70).+ Ẹ́kísódù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Gbogbo ọmọ* tí wọ́n bí fún Jékọ́bù* jẹ́ àádọ́rin (70),* àmọ́ Jósẹ́fù ti wà ní Íjíbítì.+ Ìṣe 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí náà, Jósẹ́fù ránṣẹ́ pe Jékọ́bù bàbá rẹ̀ àti gbogbo mọ̀lẹ́bí rẹ̀ láti ibẹ̀,+ gbogbo wọn* lápapọ̀ jẹ́ márùndínlọ́gọ́rin (75).+
14 Torí náà, Jósẹ́fù ránṣẹ́ pe Jékọ́bù bàbá rẹ̀ àti gbogbo mọ̀lẹ́bí rẹ̀ láti ibẹ̀,+ gbogbo wọn* lápapọ̀ jẹ́ márùndínlọ́gọ́rin (75).+