24 Ẹ wá sọ pé, ‘Jèhófà Ọlọ́run wa ti fi ògo rẹ̀ àti títóbi rẹ̀ hàn wá, a sì ti gbọ́ ohùn rẹ̀ látinú iná.+ Òní la rí i pé Ọlọ́run lè bá èèyàn sọ̀rọ̀ kí onítọ̀hún má sì kú.+
26 Mo bẹ̀rẹ̀ sí í bẹ Jèhófà, mo sì sọ pé, ‘Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, má pa àwọn èèyàn rẹ run. Ohun ìní* rẹ ni wọ́n jẹ́,+ àwọn tí o fi títóbi rẹ rà pa dà, tí o sì fi ọwọ́ agbára mú kúrò ní Íjíbítì.+