- 
	                        
            
            Sáàmù 78:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        22 Torí pé wọn ò ní ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run;+ Wọn ò gbẹ́kẹ̀ lé e pé ó lágbára láti gbà wọ́n là. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Hébérù 3:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        16 Torí, àwọn wo ló gbọ́, síbẹ̀ tí wọ́n mú un bínú gidigidi? Ní tòótọ́, ṣebí gbogbo àwọn tí Mósè kó jáde ní Íjíbítì ni?+ 
 
-