Diutarónómì 14:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Iwájú Jèhófà Ọlọ́run rẹ ni kí o ti máa jẹ ìdá mẹ́wàá ọkà rẹ, wáìnì tuntun rẹ, òróró rẹ àti àwọn àkọ́bí nínú ọ̀wọ́ ẹran àti agbo ẹran rẹ, ní ibi tó yàn pé kí orúkọ rẹ̀ máa wà,+ kí o lè kọ́ láti máa bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run rẹ nígbà gbogbo.+ 2 Kíróníkà 7:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà wá fara han Sólómọ́nì+ ní òru, ó sì sọ fún un pé: “Mo ti gbọ́ àdúrà rẹ, mo sì ti yan ibí yìí fún ara mi láti jẹ́ ilé ìrúbọ.+
23 Iwájú Jèhófà Ọlọ́run rẹ ni kí o ti máa jẹ ìdá mẹ́wàá ọkà rẹ, wáìnì tuntun rẹ, òróró rẹ àti àwọn àkọ́bí nínú ọ̀wọ́ ẹran àti agbo ẹran rẹ, ní ibi tó yàn pé kí orúkọ rẹ̀ máa wà,+ kí o lè kọ́ láti máa bẹ̀rù Jèhófà Ọlọ́run rẹ nígbà gbogbo.+
12 Jèhófà wá fara han Sólómọ́nì+ ní òru, ó sì sọ fún un pé: “Mo ti gbọ́ àdúrà rẹ, mo sì ti yan ibí yìí fún ara mi láti jẹ́ ilé ìrúbọ.+