Diutarónómì 18:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “‘Tí wòlíì èyíkéyìí bá kọjá àyè* rẹ̀, tó sọ̀rọ̀ lórúkọ mi, ọ̀rọ̀ tí mi ò pa láṣẹ fún un pé kó sọ tàbí tó sọ̀rọ̀ lórúkọ àwọn ọlọ́run mìíràn, wòlíì yẹn gbọ́dọ̀ kú.+
20 “‘Tí wòlíì èyíkéyìí bá kọjá àyè* rẹ̀, tó sọ̀rọ̀ lórúkọ mi, ọ̀rọ̀ tí mi ò pa láṣẹ fún un pé kó sọ tàbí tó sọ̀rọ̀ lórúkọ àwọn ọlọ́run mìíràn, wòlíì yẹn gbọ́dọ̀ kú.+