4 Tí wọ́n bá sọ fún ọ tàbí tí o gbọ́ nípa rẹ̀, kí o wádìí ọ̀rọ̀ náà dáadáa. Tó bá jẹ́ òótọ́ ni+ ohun ìríra yìí ṣẹlẹ̀ ní Ísírẹ́lì, 5 kí o mú ọkùnrin tàbí obìnrin tó ṣe ohun burúkú yìí jáde wá sí ẹnubodè ìlú, kí ẹ sì sọ ọkùnrin tàbí obìnrin náà ní òkúta pa.+