-
Diutarónómì 6:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Kí o máa ṣe ohun tó tọ́, tó sì dáa ní ojú Jèhófà, kí nǹkan lè máa lọ dáadáa fún ọ, kí o lè wọ ilẹ̀ dáradára tí Jèhófà búra fún àwọn baba ńlá rẹ nípa rẹ̀, kí o sì gbà á,+
-