Diutarónómì 26:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Tí o bá ti kó gbogbo ìdá mẹ́wàá+ èso ilẹ̀ rẹ jọ tán ní ọdún kẹta, ọdún ìdá mẹ́wàá, kí o fún ọmọ Léfì, àjèjì, ọmọ aláìníbaba* àti opó, kí wọ́n sì jẹ ẹ́ yó nínú àwọn ìlú* rẹ.+
12 “Tí o bá ti kó gbogbo ìdá mẹ́wàá+ èso ilẹ̀ rẹ jọ tán ní ọdún kẹta, ọdún ìdá mẹ́wàá, kí o fún ọmọ Léfì, àjèjì, ọmọ aláìníbaba* àti opó, kí wọ́n sì jẹ ẹ́ yó nínú àwọn ìlú* rẹ.+