Diutarónómì 28:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà máa ṣí ọ̀run, ilé ìkẹ́rùsí rẹ̀ tó dáa fún ọ, láti rọ òjò sórí ilẹ̀ rẹ ní àkókò+ rẹ̀, kó sì bù kún gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. O máa yá ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè ní nǹkan, àmọ́ kò ní sóhun tó máa mú kí o yá+ nǹkan.
12 Jèhófà máa ṣí ọ̀run, ilé ìkẹ́rùsí rẹ̀ tó dáa fún ọ, láti rọ òjò sórí ilẹ̀ rẹ ní àkókò+ rẹ̀, kó sì bù kún gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. O máa yá ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè ní nǹkan, àmọ́ kò ní sóhun tó máa mú kí o yá+ nǹkan.