Mátíù 26:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí ìgbà gbogbo ni àwọn aláìní wà láàárín yín,+ àmọ́ ìgbà gbogbo kọ́ ni màá wà láàárín yín.+