Òwe 3:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Má fawọ́ ohun rere sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ àwọn tó yẹ kí o ṣe é fún*+Tó bá wà níkàáwọ́ rẹ* láti ṣe é.+ Mátíù 5:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Tí ẹnì kan bá ń béèrè nǹkan lọ́wọ́ rẹ, fún un, má sì yíjú kúrò lọ́dọ̀ ẹni tó fẹ́ yá nǹkan* lọ́wọ́ rẹ.+ Lúùkù 12:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ẹ ta àwọn ohun ìní yín, kí ẹ sì ṣe ìtọrẹ àánú.*+ Ẹ ṣe àwọn àpò owó tí kì í gbó, ìṣúra tí kò lè kùnà láé sí ọ̀run,+ níbi tí olè kankan kò lè sún mọ́, tí òólá* kankan ò sì lè jẹ ẹ́ run.
42 Tí ẹnì kan bá ń béèrè nǹkan lọ́wọ́ rẹ, fún un, má sì yíjú kúrò lọ́dọ̀ ẹni tó fẹ́ yá nǹkan* lọ́wọ́ rẹ.+
33 Ẹ ta àwọn ohun ìní yín, kí ẹ sì ṣe ìtọrẹ àánú.*+ Ẹ ṣe àwọn àpò owó tí kì í gbó, ìṣúra tí kò lè kùnà láé sí ọ̀run,+ níbi tí olè kankan kò lè sún mọ́, tí òólá* kankan ò sì lè jẹ ẹ́ run.