Ẹ́kísódù 34:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 “Kí ẹ máa ṣe Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú.+ Ẹ jẹ búrẹ́dì aláìwú bí mo ṣe pa á láṣẹ fún yín; ọjọ́ méje ni kí ẹ fi ṣe é ní àkókò rẹ̀ nínú oṣù Ábíbù,*+ torí oṣù Ábíbù lẹ kúrò ní Íjíbítì.
18 “Kí ẹ máa ṣe Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú.+ Ẹ jẹ búrẹ́dì aláìwú bí mo ṣe pa á láṣẹ fún yín; ọjọ́ méje ni kí ẹ fi ṣe é ní àkókò rẹ̀ nínú oṣù Ábíbù,*+ torí oṣù Ábíbù lẹ kúrò ní Íjíbítì.