Mátíù 26:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ní ọjọ́ kìíní Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú,+ àwọn ọmọ ẹ̀yìn wá sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n bi í pé: “Ibo lo fẹ́ ká ṣètò fún ọ láti jẹ Ìrékọjá?”+
17 Ní ọjọ́ kìíní Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú,+ àwọn ọmọ ẹ̀yìn wá sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n bi í pé: “Ibo lo fẹ́ ká ṣètò fún ọ láti jẹ Ìrékọjá?”+