15 Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi jẹ búrẹ́dì aláìwú.+ Lọ́jọ́ kìíní, kí ẹ mú àpòrọ́ kíkan kúrò ní ilé yín, kí ẹ pa ẹni* tó bá jẹ ohun tó ní ìwúkàrà* láti ọjọ́ kìíní títí dé ìkeje ní Ísírẹ́lì.
7 Búrẹ́dì aláìwú ni kí ẹ jẹ fún ọjọ́ méje náà;+ ohunkóhun tó bá ní ìwúkàrà ò gbọ́dọ̀ sí lọ́wọ́ yín,+ kò sì gbọ́dọ̀ sí àpòrọ́ kíkan lọ́wọ́ yín ní gbogbo ilẹ̀* yín.