-
Léfítíkù 23:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àmọ́ kí ẹ ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà fún ọjọ́ méje. Ní ọjọ́ keje, àpéjọ mímọ́ máa wà. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára kankan.’”