ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 23:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Ọjọ́ méje ni kí ẹ fi ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. Ní ọjọ́ kẹjọ, kí ẹ ṣe àpéjọ mímọ́,+ kí ẹ sì ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. Àpéjọ ọlọ́wọ̀ ni. Ẹ ò gbọ́dọ̀ ṣe iṣẹ́ agbára kankan.

  • Léfítíkù 23:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Ní ọjọ́ kìíní, kí ẹ mú èso àwọn igi ńláńlá, àwọn imọ̀ ọ̀pẹ,+ àwọn ẹ̀ka igi eléwé púpọ̀ àti àwọn igi pọ́pílà tó wà ní àfonífojì, kí ẹ sì yọ̀+ níwájú Jèhófà Ọlọ́run yín fún ọjọ́ méje.+

  • Nehemáyà 8:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ojoojúmọ́ ni wọ́n ń ka ìwé Òfin Ọlọ́run tòótọ́,+ láti ọjọ́ àkọ́kọ́ títí di ọjọ́ tó kẹ́yìn. Wọ́n sì fi ọjọ́ méje ṣe àjọyọ̀ náà, ní ọjọ́ kẹjọ, wọ́n ṣe àpéjọ ọlọ́wọ̀, gẹ́gẹ́ bí òfin ṣe sọ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́