-
Diutarónómì 13:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Nígbà náà, ẹ̀rù á ba gbogbo Ísírẹ́lì tí wọ́n bá gbọ́, wọn ò sì ní dán ohun tó burú bẹ́ẹ̀ wò mọ́ láàárín rẹ.+
-
-
Diutarónómì 19:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Tí àwọn yòókù bá gbọ́, ẹ̀rù á bà wọ́n, wọn ò sì ní ṣe irú ohun tó burú bẹ́ẹ̀ mọ́ láé láàárín rẹ.+
-