ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 20:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 “Tí o bá lọ bá àwọn ọ̀tá rẹ jagun, tí o sì rí àwọn ẹṣin, àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti àwọn ọmọ ogun wọn tí wọ́n pọ̀ rẹpẹtẹ jù ọ́ lọ, má bẹ̀rù wọn, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ tó mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì wà pẹ̀lú rẹ.+

  • 2 Sámúẹ́lì 8:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Dáfídì gba ẹgbẹ̀rún kan ó lé ọgọ́rùn-ún méje (1,700) agẹṣin àti ọ̀kẹ́ kan (20,000) ọmọ ogun tó ń fẹsẹ̀ rìn lọ́wọ́ rẹ̀. Dáfídì sì já iṣan ẹsẹ̀* gbogbo àwọn ẹṣin tó ń fa kẹ̀kẹ́ ogun, àmọ́ ó dá ọgọ́rùn-ún (100) lára àwọn ẹṣin+ náà sí.

  • Sáàmù 20:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Àwọn kan gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ẹṣin, àwọn míì sì gbẹ́kẹ̀ lé ẹṣin,+

      Àmọ́, àwa ń ké pe orúkọ Jèhófà Ọlọ́run wa.+

  • Òwe 21:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Èèyàn lè ṣètò ẹṣin sílẹ̀ de ọjọ́ ogun,+

      Àmọ́ ti Jèhófà ni ìgbàlà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́