Sáàmù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ṣùgbọ́n òfin Jèhófà máa ń mú inú rẹ̀ dùn,+Ó sì ń fi ohùn jẹ́ẹ́jẹ́ẹ́ ka* òfin Rẹ̀ tọ̀sántòru.+ Sáàmù 119:97 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 97 Mo mà nífẹ̀ẹ́ òfin rẹ o!+ Àtàárọ̀ ṣúlẹ̀ ni mò ń ronú lé e lórí.*+