Nọ́ńbà 20:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Síbẹ̀ ó sọ pé: “O ò gbọ́dọ̀ kọjá.”+ Ni Édómù bá kó ọ̀pọ̀ èèyàn àti àwọn ọmọ ogun tó lágbára* jáde wá pàdé rẹ̀. 21 Bí Édómù kò ṣe jẹ́ kí Ísírẹ́lì gba ilẹ̀ òun kọjá nìyẹn; torí náà, Ísírẹ́lì yí pa dà lọ́dọ̀ rẹ̀.+
20 Síbẹ̀ ó sọ pé: “O ò gbọ́dọ̀ kọjá.”+ Ni Édómù bá kó ọ̀pọ̀ èèyàn àti àwọn ọmọ ogun tó lágbára* jáde wá pàdé rẹ̀. 21 Bí Édómù kò ṣe jẹ́ kí Ísírẹ́lì gba ilẹ̀ òun kọjá nìyẹn; torí náà, Ísírẹ́lì yí pa dà lọ́dọ̀ rẹ̀.+