-
Ìsíkíẹ́lì 21:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Torí ọba Bábílónì dúró ní oríta náà, níbi tí ọ̀nà ti pín sí méjì, kó lè woṣẹ́. Ó mi àwọn ọfà. Ó wádìí ọ̀rọ̀ lọ́dọ̀ àwọn òrìṣà* rẹ̀; ó fi ẹ̀dọ̀ woṣẹ́.
-