Mátíù 5:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 Kí ẹ jẹ́ pípé gẹ́lẹ́,* bí Baba yín ọ̀run ṣe jẹ́ pípé.+ 2 Pétérù 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, bí ẹ ṣe ń retí àwọn nǹkan yìí, ẹ sa gbogbo ipá yín kó lè bá yín nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín láìní èérí àti àbààwọ́n àti ní àlàáfíà.+
14 Nítorí náà, ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, bí ẹ ṣe ń retí àwọn nǹkan yìí, ẹ sa gbogbo ipá yín kó lè bá yín nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín láìní èérí àti àbààwọ́n àti ní àlàáfíà.+