Jòhánù 17:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 torí pé àwọn ọ̀rọ̀ tí o sọ fún mi ni mo ti sọ fún wọn,+ wọ́n sì ti gbà á, ó dájú pé wọ́n ti wá mọ̀ pé mo wá bí aṣojú rẹ,+ wọ́n sì ti gbà gbọ́ pé ìwọ lo rán mi.+
8 torí pé àwọn ọ̀rọ̀ tí o sọ fún mi ni mo ti sọ fún wọn,+ wọ́n sì ti gbà á, ó dájú pé wọ́n ti wá mọ̀ pé mo wá bí aṣojú rẹ,+ wọ́n sì ti gbà gbọ́ pé ìwọ lo rán mi.+